Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà

Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà
October 20, 2026

Àmì Ẹranko buburu naa 54-0513

Ijọ kookan, lo ní ẹ̀kọ́ ijo tire.

Ní ọ̀pọ̀ ìgbà, nínú àwọn ijọ eleyameya, nínú àwọn ijo eleko adamo, wọ́n ní agbelero eko ijo tiwon. Wọ́n sì n’ dúró lórí eko náà, Won nwipe “Èyí ni ohun ti awa gbàgbọ́” Alùfáà ibá tile ni erò miran, ó gbọ́dọ̀ wàásù gege bi eko ijo won, nítorí pé ó je omo ijọ eleyameya naa.

Sugbon níhín, a kò ní eko adamo kankan bí kò ṣe Kristi, ìyẹn ni eko ijo tiwa; kò sì sí òfin kan bí kò ṣe ìfẹ́; kò sí ìwé kan bí kò ṣe Bíbélì. Kristi sì ni Orí wa; Bíbélì sì ni ìwé kika wa; gbogbo agbayé si ni ìjọ mi. Nítorí náà mo fẹ́ràn—mo fẹ́ràn láti maa wàásù lọ́nà tí mo rò pé Olorun ń darí mi láti wàásù, àti bí mo ṣe ń rí i.

Oúnjẹ Ojoojúmọ́

Ẹni tí ó bá ní etí láti gbọ́, kí ó gbọ́.
Mátíù 11:15

An Independent Church of the WORD,