Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà

Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà
October 22, 2026

Iwe Hébérù Orí Kejì 2 57-0825E

Ó, e je ka dúró je fun iṣẹ́jú kan péré! Ta tile ni ẹ́ gaan? Kí ni itumo iṣẹ́ tí o n se yen? Tàbí kí ni ilé kékeré tí a ko yen jasí? Kí ni ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tí a ra jasí ?

Iwo odomọbìnrin arewa, to rewa loju, kini ewa re jasii? Ẹ̀yin ọ̀dọ́mọkùnrin tí e ní irun dídán yoyo, èjìká tí ó gun rege, ẹ̀yin yin yóò tẹ̀ lọjọ́ kan, nígbà tí e bá ti darugbo.

Ṣùgbọ́n, ìbùkún ni fún Olúwa! Ẹ̀yin ní ẹ̀mí tí a tún bí. Ẹ̀yin yóò wà láàyè títí láéláé, nítorí pé Ó di eyín, kí ẹ̀yin lè di oun, kí ẹ̀yin lè dabi re nípasẹ̀ oore-ọ̀fẹ́ Rẹ̀. O si ti pese aye sile fun yin

O! Àwa tí a rò pé a ni aṣọ to po, àsi tun ni oúnjẹ díẹ̀ nilé, kí la je? Ọlọ́run lè gbà áa pada laarin ìṣẹ́jú kan. Ẹ́emí rẹ gan-an wa lọwọ́ Rẹ̀. Óun sì wà láàrín wa láti wo àwọn aláìsàn sàn, láti kéde àti láti jẹ́wọ́, àti láti sọtẹ́lẹ̀, àsepe si ní Olorun ma nse gbogbo re. Oro wa je logun debiwipe o da iye pada sinu ẹja kekere kan tí ó ti kú, ní àárín wa. Jehofa to wa layiká wa, Jehofa to wa nínú wa, emi ni ton je emini ńlá àti alágbára.

Oúnjẹ Ojoojú

Nitorina mo wi fun nyin, Ẹ máṣe ṣe aniyan nitori ẹmí nyin ohun ti ẹ ó jẹ, ati fun ara nyin ohun ti ẹ o fi bora. Ẹmí kò ha jù onjẹ lọ? tabi ara ni kò jù aṣọ lọ?
Mátíù 6:25

An Independent Church of the WORD,