26-0906 lori Awon Wundia Mewa, Ati Oke Meji ole Egbaaji Awon Omo Juu

Iyawo Kristi owọn, eje ki a pejopo ni Ojo aiku ni dede ago mejila, akoko Jeffersonville, làti gbo ìwasu 69-1211M, lori Awon Wundia Mewa, Ati Oke Meji ole Egbaaji Awon Omo Juu.
Arákùnrin Joseph Branham