Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà
October 19, 2026
Ìja laarin esin Kristiani àti Ìbọ̀rìṣà 61-1217
…Awòrán ààyè ti Ọlọ́run alààyè.laje. Lẹ́yìn náà, a ti kú sí ara wa, a ti jíwa dìde pẹ̀lú Rẹ̀. E fetísílẹ̀ nísinsìnyí, e fetí sí èyí, Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ tún di ara nínú wa leekan si (Ó, Arákùnrin Neville!) Wò ó! Kí ni? Kìí ṣe ọlọ́run awon itan àròsọ kan, tabi tí akan nfori ro to jókòó sita nibe yen, bí kò ṣe Ọlọ́run alààyè. Kí ni Ọlọ́run alààyè? Ọ̀rọ̀ ton gbe ninú rẹ tí ó ń sọ ara rẹ̀ di arigbamu. Ògo ni fún Ọlọ́run! Ó!, mo mọ̀ pé o n rò wipé mo jẹ́ gbara yile mímọ́, bóyá nkàn ti mosi je nìyẹn o. Ṣùgbọ́n, ó! arákùnrin, nje o rí i? Ati ni iṣẹ́gun lórí gbogbo ìjọ, ìṣẹ́gun lórí gbogbo eko adamo, Ọlọ́run alààyè tí a fi hàn nínú tẹ́ḿpìlì ààyè, àti Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí í ṣe Ọlọ́run, tí a sọ di ara nínú yín. Eese? Ẹ jókòó ní ìbi giga ninu àwọn ọ̀run, ẹ ti bori ohun gbogbo, nínú Kristi Jésù. Àmín!
Oúnjẹ Ojoojúmọ́
Ẹnyin kò mọ̀ pe ẹ̀ya-ara Kristi li ara nyin iṣe? …..
1 Kọ́ríńtì 6:15