Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà

Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà
October 13, 2026

Ìṣọ̀kan 62-0211

Awà ree ní igba ìkẹyìn, a ń wa láti ìlà-oòrùn àti ìwọ̀-oòrùn, àríwá àti gúúsù. Kí ni a ń ṣe? A ń múra sílẹ̀ fún Ìgbàsókè naa. A ń múra sílẹ̀ fún…A wa ni idakeje fún ìṣẹ́jú díẹ̀ títí Olorun yióò fi fi emi mimo kun gbogbo isan ara wa patapata. Nígbà náà ni iyawo yóò gòkè lọ. Kaasa! Olorun npè àwọn ènìyàn papọ̀ sodo ara Rẹ̀, nínú ìṣọ̀kan tòótọ́ pẹ̀lú Rẹ̀, nítorí pé Ẹ̀mí Mímọ́ Rẹ̀ nikan ṣoṣo ni. “Nípa Ẹ̀mí kan na ni a ti bamitiisi olukuluku wa sínú Ara kan naa, gbogbó wa làpapọ̀ si je Ara Jésù Kristi.” Jésù Kristi sí ń gbé pẹ̀lú Ẹ̀mí Rẹ̀ nínú ara wa, o ń ṣe itoju Ìjọ ó sì o ń ṣe àwọn ohun kan náà tí Ó ti ṣe ni ígbà atijo, gẹ́gẹ́ bí ise àmì, gẹ́gẹ́ bí opagun sí gbogbó agbayé, wipé a wà ní ígbà ìkẹyìn, a ń múra sílẹ̀ fún Ìgbàsókè. Ah, mo feran Rẹ̀, Iwo nkọ́?

Ounje Ojoojúmọ́

Logan, ni iṣẹ́ju, nigba ipè ikẹhin: nitori ipè yio dún, a o si jí awọn okú dide li aidibajẹ, a ó si pawalara dà.
1 Kọ́ríńtì 15:52

An Independent Church of the WORD,