Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà
October 10, 2026
Jobu 55-0223
Ọlọ́run ń mu ohùn gbogbo sise pọ̀ si rere fún àwọn tí o fẹ́ràn Rẹ̀, báwo ni o ṣe wa le pàdánù? O kò lè pàdánù; kò sí boo se fe pàdánù.
Iba dara ki Ìjọ lè mo asiri yi. Tí e bá lè rí ipò yin nínú Kristi, gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí yóò kàn poora bi ojiji ni. Nitooto, gbogbo àwon tí ó bá to Ọlọ́run wa, gbọ́dọ̀ ní awon òjìji, àti àwọn ìdanwò, àti ìbẹ̀rù, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, ṣùgbọ́n má ṣe jẹ́ kí won ko irewesi ba okan re. Ijìyà díẹ̀ yi fúngbà díẹ̀ ni, nitori awa mọ̀ pé ògo Ọlọ́run yóò farahàn ní ọjọ́ ìkẹyìn nígbà tí Jésù bá dé, nígbà tí a ó dà bí Rẹ̀? Olorun ń jeki ohùn gbogbo sise papọ̀ ni. Nje o mọ̀, bóyá tí o bá ṣàìsàn, tabi ti ohun kan ba ṣẹlẹ̀ sí ọ, pé boya Ọlọ́run ṣe èyí láti tubo fa e mọ́ra si ni?
Oúnjẹ Ojoojúmọ́
Nitori a wà láàyè nisisiyi, bi ẹnyin ba duro ṣinṣin ninu Oluwa.
1 Tẹsalóníkà 3:8