Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà
July 9, 2026
Emaa gbọ́ tirẹ̀ 58-0126
Ohun tí kò tọ́ ni kí obìnrin gé irun rẹ̀. Bíbélì lo sọ bẹ́ẹ̀. Ó sì ń f’àbùkù kan ọkọ rẹ̀ ní nigbà tí ó bá ṣe bẹ́ẹ̀. Ìjọ kì í si ṣe bẹ́ẹ̀ tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n lónìí, nítorí pé àga ìwaasu ti di aláìlera, wọ́n máa ń ṣe é. Àwọn obìnrin sì máa ń wọ aṣọ penpe wọ̀nyí tí ó dàbí aṣọ ọkùnrin, yeri ti ko bale ti won la nisale, tàbí ki ti e ni oruko tí wọ́n máa ń pè wọ́n?. Ṣé o mọ̀ pé Bíbélì sọ pé ó jẹ́ ohun ẹ́gbin àti ìríra lójú Ọlọ́run. Ejo woni Ẹ̀mí Mímọ́ maa rò nígbà tí Ó bá njise fun Ọlọ́run Baba, nipa bí àwọn ọmọbìnrin Ìjọ ṣe ń ṣe?
Oúnjẹ Ojoojúmọ́
Ṣùgbọ́n bí obìnrin bá ní irun gígùn, ó jẹ́ ògo fún un: nítorí a fi irun rẹ̀ fún un gẹ́gẹ́ bí ìbòrí.
1 Kọ́ríńtì 11:15