Ọ̀rọ̀ Ọjọ́ náà
July 27, 2026
Àgbàyanu 56-0129
Àgbegbe to yini ka loma n sokun fa iṣẹ́ ìyanu, iṣẹ́ ìyanu Ha! ,àti agbára Ọlọ́run láàrín àwọn ènìyàn. Ó jẹ́ àgbegbe to yi àwọn ènìyàn ka. Nígbà tí àwọn ènìyàn bá dé ibi kan tí wọ́n ń ronú bi eniyan eleran ara, tí wọ́n ń ṣe kàyéfì, tí wọ́n ń ba ara wọn jiyan, tí wọ́n ń ronú, tí gbogbo wọn sì ni ede aiyede larin won, tí wọn kò sì mọ ibi tí wọ́n dúró sí, ti ìdajì wọn Kini imo Bibeli, báwo ni ẹ ṣe lè retí pé kí agbgbe ti o yiwon ka wa ni titọ́? Ẹ kò lè ṣe é; kò ní tọ́. E gbọ́dọ̀ wà ní ìṣọ̀kan, ibì kan, kí ẹ sì jumo ni ète kanna pelu ohun kan, nígbà náà ni ẹ ó rí nkan tí yió ṣẹlẹ̀.
Oúnjẹ Ojoojúmọ́
Ẹ mu ayọ̀ mi kún, ki ẹnyin ki o le jẹ oninu kanna, ki imọ̀ nyin ki o ṣọkan, ki ẹ si ni ọkàn kan.
Filippi 2:2